12/14/2023
E gbọ ọrọ ọgbọn latí kọ ẹkọ
ojú ìwé yíì ni yíò ma kó ọmọdé àti àgbàlagbà ní èdè, àṣà àti ìtàn Yorùbá
E gbọ ọrọ ọgbọn latí kọ ẹkọ
Wọn ní kí olójú rogodo sọra fún kinkin ata, kí alaso alaa funfun gbòò sọra fún kinkin epo.
Bí ilẹ̀ ṣe ń mọ tí ilẹ̀ n ṣú, beeni ọjọ́ ta jẹ ènìyàn ń sunmọ, bẹẹ si ni ọjọ ta jáde láyé pẹ̀lú, ẹ jẹ ká gbé ile ayé ṣé réré, ire ohh
Ẹ káàbò sórí ojú ìwé ìmò l'àgbà