Dairotul-Ulum Arobiyyat Wal-Islamiyyat

Dairotul-Ulum Arobiyyat Wal-Islamiyyat

Share

Dairotul-ulum Arabic & Islamic College, Otun Area, Saki, Oyo state, Nigeria and also don’t forget to like this page. Ma ha Sallam.

Assalam Alaekum Warohamatullahi Wabarokatuhu
TRUTHFUL CALLING TO EVERY HUMAN BEINGS
DAIROTUL-ULUM AROBIYYAT WAL-ISLAMIYYAT, located at
Otun Area, Saki, Oyo State of Nigeria, calls on all people, Male, Female, Old, Youth and Young to come and learn the truthful knowledge of Arabic language and all Sharihatul-Islam, as laid down by Almighty ALLAHU, from the elementary stage to
other higher grades.
*

19/07/2023
18/10/2022

*Assalamu Alaekum Warohamatullahi Wabarokatuhu*
IKEDE ODODO FUN GBOGBO ENIYAN

Ile-Eko DAIROTUL-ULUM AROBIYYAT WAL-ISLAMIYYAT, to wa ni adugbo otun , ilu Saki, ipinle Oyo, Nigeria. Pe gbogbo eniyan patapata, l’okunrin, l’obinrin o-do ati agbalagba, la ti wa ko eko imo ijinle Ododo Ede Arabic ( Larubawa) pelu gbogbo awon imo ododo Sharihatul Islam Olohun ALLAHU patapata, lati ipele ibere t**i de awon ipele giga lorisirisi.
Ofe ni gbigba iwe igbaniwole (Admission Form) kiko orisirisi awon eko na ni ipele-ipele re ati gbigba awon orisirisi Shahadat( Certificates) ni ipele eko re, ofe ni gbogbo won patapata.
Gbogbo ojo Alaruba (Wednesday) ni ojo ti e o ma wa gba iwe igbaniwole na (Admission Form) ni deede agogo Mesan Owuro geere (9:00am) ni ile-Eko yi. Ki e tete wa gba (Form) na bayi, ki asiko re to koja.
Sugbon ki e wa gbo ekunrere alaye ni ile-Eko yi siwaju ki e to wa gba (Form) naa.
Awon Ojo Ikeko niyi: Ojo Saturday ati Sunday lati Agogo Mejo Owuro t**i di Agogo Meta Osan (8:00am – 3:00pm) pelu ojo Monday t**i di Ojo Wednesday Agogo Merin Irole di Agogo Mefa-Abo Irole (4:00pm – 6:30pm).
Gbogbo Awon Eko ati imo – Ododo Sharihatul Islam yi, ko si fun sise Ise Alfaa rara lona eyikeyi tabi Jalabi toripe iro,itanje,gbajue loje, sise ebo si Olohun ALLAHU si ni pelu, ise Esu(SHAETOONI) ni sise ise Alfaa je lona eyikeyi tabi jalabi toripe ibinu Olohun (ALLAHU) ni laiye ati saare pelu Ojo Al-kiyyaamat. Ki e jawo nibe lati akoko yi lo patapata, ki e wa ise alubarika miran se, bakanna ki e jawo nibi gbogbo awon esin Adadasile eyikeyi (IFE INU) tin je (BIDHAT).
Nitori eleyi, o je oranyan dandan fun gbogbo awa omo eda eniyan patapata, lati wa ko eko imo ododo Shaarihatul Islam Olohun ALLAHU yi, ki isemi aiye wa yi to dopin. (Al-Quran:- Surotu Al-Imroon Ayat 18, Surotu Al-Imroon Ayat 85, Surotu Nnisaahi Ayat 119-121 ati Surotu Dhariyat Ayat 56-58. ki e je ki gbogbo awon eniyan gbo ikede yi ati pe ki gbogbo awon eniyan patapata jina si awon Alfaa ti nse ise Afaa lona eyikeyi tabi Jalabi, ki Olohun ALLAHU le yonu si gbogbo wa ati imona Ododo.
( Aaminu)
Ma ha Sallam.
*Olukede: MUDIR ILE EKO DAIROTUL-ULUM, OTUN, SAKI, OYO STATE OF NIGERIA*

Want your school to be the top-listed School/college in Saki?

Click here to claim your Sponsored Listing.

Location

Category

Website

Address


Otun Area Saki
Saki
234