Markazu Dhikril Hakeem

Markazu Dhikril Hakeem This is a page for awareness of Arabic training and islamic knowledge in which will make you be more enlightened deeply.

It is a platform whereby you admit to bring your children to learn arabic language and islamic knowledge.

O kú ọjọ́ ìbí, Khadeejah Alli🥳Òròmodìẹ ní ń di àkùkọ. Ìdùnnú òbí ni kí ọmọ dàgbà, kó yàn, kó yanjú. Gbogbo òbí tó ń tọrọ...
10/07/2024

O kú ọjọ́ ìbí, Khadeejah Alli🥳

Òròmodìẹ ní ń di àkùkọ. Ìdùnnú òbí ni kí ọmọ dàgbà, kó yàn, kó yanjú. Gbogbo òbí tó ń tọrọ ọmọ kọ́ ni elédùmarè fún, gbogbo ẹni tó bí kọ́ ni ó dàgbà t'ẹ́gbẹ́, a dúpẹ́ fún olúwa tí bíbí àti ìdàgbà rẹ ń ṣojú wa.

Olùdásílẹ̀ àti gbogbo olùkọ́ ilé ìwé LUCENT kí ọ kú ọjọ́ ìbí òní. Ẹ̀mí rẹ óó gùn, wàá pẹ́ bí mópẹ́ tíí pẹ́, wàá dàgbà, wàá d'ògbó, wàá di irún d'gba fún àwọn òbí rẹ, wàá ṣe àǹfààní fún ayé, iná ògo rẹ yóò tàn kárí ayé lọ́lá Allahu. Aṣẹ́nilórí ò níí sẹ́ ọ lórí, ìràwò rẹ yóò tàn kò níí wọmi, oò ní sọnù láàrin wa.

Bí o ṣe ṣe ayẹyẹ ọjọ́ ìbí lónìí, wàá ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún láyé nínú ọlá ńlá, àgbéga àti àìkú baálẹ̀ ọrọ̀. Igba ọdún, ọdún kan ni ooo🥳!

LUCENT PRIVATE SCHOOLS
Markazu Dhikril Hakeem

Dear student, Happy Birthday from the heart.Because that's where all great wishes start.Have a wonderful day. Today is y...
29/06/2024

Dear student, Happy Birthday from the heart.Because that's where all great wishes start.Have a wonderful day. Today is your birthday, may all things go to your way.Wish you a many many happy returns of the day. May God bless you with health, wealth and prosperity in your life. HAPPY BIRTHDAY IMRAN JUBRIL.
Study hard, work hard and don’t forget to live a healthy life may Allah be with you. I wish you but the best on your special day!
As long as you work hard and never stop believing in yourself, good luck and success shall always accompany you.
ONCE AGAIN HAPPY BIRTHDAY TO YOU IMRAN JUBRIL

From the Management
LUCENT PRIVATE SCHOOLS 🏫

08/12/2023
19/07/2023

As-salam alaikum warahmotullahi wa barakatuhu
*_Please note_* : there is holiday in the madrasah today due to *hijrah* celebration

All students should resume respectively tomorrow *INSHALLAH*

يارب إن الهجره أجر الآخرة الله

فاغفر للأنصار والمهاجره

Address

Ade Adesanya Street, Arigbawonwo & Omu Aleku
Mowe

Telephone

+2347057242084

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Markazu Dhikril Hakeem posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The School

Send a message to Markazu Dhikril Hakeem:

Shortcuts

Share

Category