Bible:- question and answer in Bible with verse of the day

Bible:- question and answer in Bible with verse of the day Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Bible:- question and answer in Bible with verse of the day, Tutor/Teacher, Ilesha.

23/02/2022

King James Bible is the true Bible version for all Christians. 2 times a day, 10 mins each time. Bible for your mood. Read the Bible everyday!

19/02/2022

EKO KIKA WA TI ONI
ROMU 6:16-19

16. Ẹnyin kò mọ̀ pe, ẹniti ẹnyin ba jọwọ ara nyin lọwọ fun bi ẹrú lati mã gbọ́ tirẹ̀, ẹrú ẹniti ẹnyin ba gbọ tirẹ̀ li ẹnyin iṣe; ibãṣe ti ẹ̀ṣẹ sinu ikú, tabi ti igbọran si ododo?

17. Ṣugbọn ọpẹ́ ni fun Ọlọrun pe, bi ẹnyin ti jẹ ẹrú ẹ̀ṣẹ rí, ẹnyin jẹ olugbọran lati ọkàn wá si apẹrẹ ẹkọ ti a fi nyin le lọwọ.

18. Bi a si ti sọ nyin di omnira kuro ninu ẹ̀ṣẹ, ẹnyin di ẹrú ododo.

19.Emi nsọ̀rọ bi enia nitori ailera ara nyin: nitori bi ẹnyin ti jọwọ awọn ẹ̀ya ara nyin lọwọ bi ẹrú fun iwa-ẽri ati fun ẹ̀ṣẹ de inu ẹ̀ṣẹ; bẹ̃ gẹgẹ ni ki ẹnyin ki o jọwọ awọn ẹ̀ya ara nyin lọwọ nisisiyi bi ẹrú fun ododo si ìwa-mimọ́.

Join us on WhatsApp
18/02/2022

Join us on WhatsApp

WhatsApp Group Invite

10/02/2022

John 14vs15 said what??

Address

Ilesha

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Bible:- question and answer in Bible with verse of the day posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share

Category