The most powerful native doctor in nigeria

The most powerful native doctor in nigeria

Share

+2349114523239,AM NATIVE DOCTOR THAT HELP WITH ROOT AND LEAVES CREATED BY GOD FOR HUMAN PURPOSE.

19/11/2025

IKỌ IFE (IKỌ ASTHMA)

Orukọ Èso Náà:- Konkan Eyinbo

Ao Wa Èyí tó ṣii tútù, Ao bọ Aṣọ Àrà rẹ, ao wa ko àwọn kóró inu rẹ kúrò. So ge sí ònà Méjì tàbí mẹta. Ao wà kò wọn sínú Omi. Ao gbe pamọ fún Ọjọ méjì (48 hours). AO máa mú idaji Glass cup.
O ma máa pọ Àwọn Ohun idiwọ .
09114523239

09/11/2025

OGUN TI AFIN GBA ISE OLOWO NLA (BIG MONEY)

CONNECTION

Igbin mẹta,
Ẹyin ibilẹ mẹta,
Iyẹ agbe Mẹta,
Iyẹ aluko Mẹta,
Ikodẹ Mẹta,
Ewe ejinrin
Imi ọjọọ niwọnba,

ao jopọ, ao lọ kuna dáadáa,
ao wa po lọsẹ dudu,

ao ko sinu ikoko ajere,ao mafi wẹ,

idi rẹ ko gbọdọ kanle mọ o
+2349114523239

Photos from The most powerful native doctor in nigeria's post 28/10/2025

IFA OSHOLE ONITIKUTI

ori aja 🐕 tutu kan, odidi akan 🦀 tope kan,ewe ọ̀gẹ̀dẹ̀ agbagba topo die,ewe itipon ola tutu,ewe sefunsefun,ewe onitikuti tutu,ewe sapo tutu,odidi atare nla kan,koro efun mewa,koro osun ọgbọ́n,ao jo won papo aolo kuna aote ni ifa osa meji aope gbólóhùn rẹ si aoro sinu ado ide nla tàbí karo sinu sere nla kan (note ori ajá yen lama kọ́kọ́ fi tẹ́lẹ̀ inu àpe o kato ko awon eroja yoku le lori) ao mafi oti tobani agbara lo laaro pelu pipe gbólóhùn re nasi

GBÓLÓHÙN RẸ 👇

Esalesa 3× Akandudu 3× Akangirigiri 3× Ajagunna 3× Awon ni baba alawo tose ifa fun Orunmila, ni joti Orunmila n sunkún ifa ọlá Oojo won ni Orunmila bawo ni ose jẹ? Orunmila ni eyin komope ni lanla ni sapo nru we ninu igbó ewu nlanla ni ọ̀gẹ̀dẹ̀ agbagba n wo Orunmila ni odi jagidi, Orunmila ni odi jagada, Emi LML tigbe ori aja wasile aye ,Orisa Oke Toda Aja loni Aja kogbodo fi ori ru ẹrú Oni ki Aja kosi mani ile lori,wagba wagba la npe aja Osa meji sebi ìwọ ni oru igba Ola Aja wasile aye lọ́jọ́ sì, Osa meji walo ru ire Aje temi Wa fun mi loni Osun loni ki Ewa fi ire aje temi sun mibo,Efun loni ki ewa mafunmi ni owo temi loni Alaja kiipe aja re ki o maje oo owo ńláńlá niki wọn oma wafi bemi ni isẹ temi loni onitikuti loti gbogbo olówó aye yi wa sọ́dọ̀ emi lml ki won maru gbogbo ola won wa funmi tori pe gbogbo ara ni sefunsefun fi nse aje aowase adura sii .

Call or WhatsApp
+2349114523239

Photos from The most powerful native doctor in nigeria's post 26/10/2025

Eyonu ifehan larin oko si aya.

Eso werenjeje

Ewe sawerepepe

Ao lo mejeji papo daada ao da sinu perfume Devine grace Ao ma fi Sara jade lararo pelu adura.
+2349114523239

13/09/2025

OGUN KOKORO OYAN
Aidan ,
Osibata tutu,
Eso teteregun tutu,
ewe agbasa .
Ao ge Aidan yen si wewe ao ko tele ape.
ao ko ewe agbasa le lori ao wa ko nkan ti o ku si ao fi omi se jinna dada ti o ba ti jinna .Ao so sori nkan ki idi re ma kanle .
LILO : AO wa sugar oni horo ( cube) eyo kan aolo sinu ogere epo pupa , ao fi pa oyan na ( the affected breast).ao wa yo Agbo yi sinu basia nla kan tabi Ike tio ba fe die kan Bi agbo yen se nyo eruku Obinrin na yio si aya de ao fi a*o bomo
Gbogbo kòkòrò naa yio bẹrẹ si yo jade
fi adura rẹ ranṣẹ
+2349114523239

05/09/2025

IFA EBE EYONU ASINA AWON AGBALAGBA

ewe ominsinmisin oniitakun,
ao lopo pelu iyere,
ao ge eyele eyikeyi kan si kekeke,
ao fi iyo ati epo se lobe, ti oba ti jin na tan ao ta oyin die si,
ao fi iyere osun te ifa Ogbe-yonu,
ao pe ofore si ao da sinu aseje yen ao koje
OFORE
oyiboyi lawo aye 3x,
ata bagbe lawo ode orun 3x,
adifa fun Orunmila
ni ijo ti n tiko le orun bo wa ile aiye,
ode ile aiye, oba Oṣo, ode ile Aiye Oba Aje,
ode ile aiye oba Esu odara, Oṣo ni nje Orunmila mo oun ni Oṣo?
Ajẹ́ ni se orunmila mo oun ni Ajẹ́,
Eṣu odara ni se Orunmila mo oun ni Eṣu odara,
Oṣo ni oun ni kin nje kẹni ose owo( business) kẹ́ni jere,
Ajẹ́ ni oun ni kii je ki eni o lowo lowo, ki eni ori aiye se,
Eṣu odara ni oun ni oun ma nfi aburu ṣe eniyan ni ode aiye,
Orunmila ni oun fi Ogbe yonu be yin lode aiye,
eje kin nkan mi o ma dayo,
ki ema le ba nkan mi je mo
nitori a kiifi eyele ṣe irana oku,
ki emale fi nkan semi laburu,
ti a ba fi oyin se obe didun lon dun,
ki oro emi Lomo L oma dun mo yin ninu,
ki won ma gbe owo nla nla ọwọ won fun mi, omode kiifi oyin senu kosin tọ́,
agbalagba oni fi iyo senu ko poṣe,
ati igi ati opẹ̀ lon sanu iyere
ki eyin omo araye ma se anu emi Lomo L lati Oni yi lo, tapatun tapasi ni eyele fi nko ire wole, ogbo eyele kan kin ni eran osi lara, ifa ma je kin mo osi
ogbe yonu loni ki gbogbo omo araye oma yonu si mi lati oni lo... ase ase ase.
Fi adura rẹ ranṣẹ

15/08/2025

OSOLE OWO TODAJU

Ao lowa Abo adie funfun pelu awon omore, odidi ologbo kan, ewe orijin 201,
ewe isaju 201, ewe ogo 201, ao gun gbogbo awon nkan won yi ninu odo, ao ko
lose, ao wafi a*o funfun tele inu ikoko ajere nla, ao wa igi akika, ao ri igi yi
mole, ao wa ko owo eyo egbefa le Ose na Lori pelu gbogbo owo tanna, ao wa
pa eje eyele funfun meji si Ori ose yi, ao fi bo, ao mafi eyele fun ni ososu, ekan
losu Ni ao mawe ose yii, ao ma daruko oye taba fe taba nwe lowo.09114523239

13/08/2025

EYONU OSHO ASINA TODAJU

Eiye Kowe dudu kan, Eku asin tutu mesan, ao fi kowe sinu, ao to eku asin yika
re, ao ko egbo tude idi mesan lelori tio bo patapata, ao ko odidi atare mesan
lelori, ao wa ko ewe aluki bomole patapata, ao jopo sinu seere kan ao mafi hot lo
laro laro pelu iwure.

To ba ti lo ise tio ba ti lo ise yi ,o ti lo ise gidi confirm ni ise ise
09114523239

23/07/2025

ONA ABAYO SII IBALOPO LOJU OORUN

Ifasehin ni Awon Aye ma n fi eyi se fun eniyan

E lo wa osun abalaye ki e loo ni ileele pelu eyo ataare meta ki e fi sin oke inkan omokunrin yin si oke ki o je meta pere, eo ji laaro kutu ja ewe ewuro ki oorun to yo yio je 201
ao gbo 200 sinu omi ao gbe si oorun laaro ao da eyo ataare 7 si ao fi owo meta daa bi agbelebu, ao fi sibe, ao gun eyokan ti o ku mose ti e le fi we leekannaaa ao se(sieve) omi yen n ao gbe omi yen ao lo fi we ose yen ni ale ki a to lo sun. Pelu ase Olohun gbogbo ona ti won ba di mon wa yo si patapata

17/07/2025

Asiri ti omo yahoo finde oyinbo mole todaju

Ewe afaimonikonimora, ewe ogbo, ewe esisi, ewe aragba, eye kowe tako tabo, eye ega, eye alanpandede, ori oka tolase lenu kan, efun ati osun, odidi atare kan, ao jo awon eroja po yato si efun ati osun yen, ao lo kunu, ao wa lo sese walo efun ati osun papo mo ebu yen, ao po gbogbore lose, ao wa fi foto clients won yen si sale igba ti ao ko ose yen si, ao fi foto yen tele igba yen, ao fi owo dollars sori foto yen, ao gbe oga aye le lori, lehin na, ao wa ko ose yen sori won ninu igba yen, ao fi iyo yi ibiti afegbe ose yi si, ao mafi we lago kan oru, ti aba fema ba oyinbo na soro, pelu adura ti aba sefe ki oyinbo na Maya owo funwa,,,,, ise yi ni etutu o, pemi fun etutu re
09114523239

Photos from The most powerful native doctor in nigeria's post 08/07/2025

Inú bíbí n kò fiṣẹ́ mi rán ọ
Ẹ̀dọ̀ fùfù n kò bẹ̀ ó lọ́wẹ̀
A dífá fún orí adẹ́tù abìwà pẹ̀lẹ́
ìwọ ni mo fiṣé mi rán.

Inú bíbí kò da nǹkan fún ni
Sùúrù ni baba ìwà
Àgbà tó ní Sùúrù ohun gbogbo ló ní
A dífá fún orí-inú,
A bù fún tòde
Orí-inú gbogbo wa kòní ba tòde
jẹ́ fún wa láṣẹ Èdùmàrè
09114523239

゚viralシfypシ゚viralシ

Photos from The most powerful native doctor in nigeria's post 06/07/2025

Aseje Oso Aje owo gidi

Odindin Ahon Malu Ebami Gesi Ona Merindinlogun (16)
Eye Onbe meta (3)
Ata Ijosi Merindinlogun (16)
Ewe Eluki(aluki) ao lo papo mon rawon apfise ahon monlu yen lepo niyo to ba tutu wo a*o to dara kawa daniyan si ko wa je
Eyin omo G aseje yi dara fun yi gidigan
Gbiyanju re wo wa dupe lowo eledumare pe o seun
+2349114523239

Want your school to be the top-listed School/college in Ijebu Igbo?

Click here to claim your Sponsored Listing.

Location

Address


No 5 Aledo Ojowo, Ita Egba
Ijebu Igbo
120105

Opening Hours

Monday 07:00 - 19:00
Tuesday 09:00 - 20:00
Wednesday 11:00 - 17:00
Thursday 09:00 - 21:00
Friday 09:00 - 20:00
Saturday 09:00 - 18:00
Sunday 12:00 - 16:00