Fakọyọ

Fakọyọ

Share

Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Fakọyọ, Education, Badagry.

28/10/2021
15/10/2021

Pari owe yii
Bi Eegun ba mú emu yo
......................

14/10/2021

Nje òye kí áta èdè wa fún àwọn òyìnbó bíi?
Àwa la lèdè àwa la ni àṣà ẹ̀jẹ̀ ká jọ jùmọ̀ gbé lárugẹ
Adéjokéewàèdèadúláwò
Live Shows by Olaide Abioye
Naijatourismradio
BBC News Yoruba
On Dun Yungba live
Fakọyọ

13/10/2021

Èdè Yorùbá ko gbọdọ PARUN....... Ajumose gbogbo wa ni. Epade wá lórí ìkànnì agbaye fàcebook Naijatourismradio pelu Fakọyọ ni àgó kan osan òní láti mọ ẹni tí yóò Fakọyọ laarin ilé iwe Soyej Group of schools àti ilé ìwé Royal Spry. Fún ìpolówó àti ṣíṣe epe Ogbeni olumide sì 07066628752 tàbí 09027210343. Èdè Yorùbá ko gbọdọ PARUN.......

12/10/2021

ÈDÈ YORÙBÁ DUN OLARINRIN. EJE KA JO JUMO GBÉ EDE ÀTI ÁSÀ YORUBA LARUGE........... ỌMỌ YORÙBÁ ATATA NÍ MI

IBEERE WA TO NÍ YÌÍ
KINI ORUKO OYÈ ỌBA ÒKEHÒ

Photos from Fakọyọ's post 09/10/2021

Àwọn ilé ìwé tó kogoja sì ipele kejì nínú idije FAKỌYỌ.

09/10/2021

Kí ni
Ọrinlelugba dín mẹta ni èdè Geesi
Ẹ̀bùn wa fún ẹni tóbá gba ìbéèrè yìí láti ọwọ Rak Development Foundation

09/10/2021

Pari owe yii
Ìgbágó Tón fi ògọ́mọ̀ ṣe yẹ̀yẹ́
.............

08/10/2021

Ile iwe Soyej Group of school yóò koju ilé ìwé Royal Spry ni OJURU ose Tonbo. Eje ka wo ẹni Toma Fakọyọ nínú ilé ìwé mejeji. Aku oju lona.

07/10/2021

Sọ ìyàtọ̀ tó wà láàrin òdú àti olúgbódi

06/10/2021

Ile iwe Soyej Fakoyo níbi idije FAKỌYỌ.

Want your school to be the top-listed School/college in Badagry?

Click here to claim your Sponsored Listing.

Location

Category

Culinary Team

Attire

Telephone

Website

Address


Badagry