Stellium School of Astrology, Numerology & Palmistry

Stellium School of Astrology, Numerology & Palmistry This is the platform where people of high caliber is geag what the future is holding

11/11/2025

Today we celebrate the heartbeat of our home,
The woman whose love has shaped my world.
You are my joy, my strength, the mother of our children
And the light that guides me through every storm.

As you step into this new year, may it overflow with blessings.
May every day bring you peace, laughter, and purpose.
Sorrow shall never find a place in your life,
Only grace, growth, and unforgettable joy.

Your days will be long and radiant,
Your path lined with favor and fulfillment.
So bask in the beauty of today, it's yours to enjoy.

Happy birthday, my love. You are cherished beyond words.

16/08/2024
26/12/2023
28/07/2021

ALAYE RANPE LORI IRAWO AWON TI WON BI LATI APRIL 22 SI MAY 21

Awon TI won waye laarin April 22 si May 21 je onirawo keji ti Ami (sign) re si je Ta**us, Venus ni o je alakoso ami irawo yi, eyi ntumosi pe ojo Friday ni ojo aseyori yin leyi to je pe nkan ti e ba dawole lawon asiko ti ko ba je awon asiko to buru ni yo ma bosi rere bakanna ti ko ba tako akosejaye yin toripe iyato wa laarin irawo ati akosejaye...

Awon onirawo yi je onisuuru lati orun wa saye sugbon e ko ki fe fi aaye gba eniti o ba few ma dari yin lona ti kosi lemi yin eyi lo ma nfun awon eyan lanfaani lati sope e je eniti o buru (stubborn).

E je olohun gooro leyiti o jasi pe e ko mo oro jeeje so toripe awon oyinbo fi maalu (Bull) se ami irawo yin eyi lo fa to fi jepe e ko mo oro jeje so, labe eyi, e gbodo sora fun nkan tabi aisan to le fe ma se gogongo tabi ona ofun yin daadaa. Leyin eyi, enife si oge sise bakanna iwa ko kan mi wa fun yin etc.

Ise bi ise owo(money), ise asaraloge tabi ti ise building materials, sand supplier, contractor etc. Je ise to ba irawo yin mu

Gbogbo ojo Friday je ojo aseyori yin, gbogbo odun ti January 1 re ba je Friday je odun aseyori yin bakanna lo tun je odun ise (work), aisan ati itoju alaisan etc.

Gbogbo Friday je ojo ti eo ma ri aseyori se lori awon adawole yin ati ojo itoju ara eni, itoju alasunmo eni pataki julo ki ise eni ma ma saisan. Odun January 1 re ba je Friday na je odun ti ao ma ri awon nkan wonyi na.

NOTE:
Gbogbo awon die ti a menuba yi je awon nkan ti awon onirawo yi yo ma koju sugbon akosejaye enikookan won ni yo pin irinajo won lotooto...

Fun alaye lekunrere Lori irawo tabi akosejaye yin call/Whatsapp 08067589328

28/07/2021

ALAYE RANPE LORI IRAWO AWON TI WON BI LATI MARCH 22 SI APRIL 21

Awon TI won waye laarin March 22 si April 21 je onirawo kinni ti Ami (sign) re si je Aries, Mars ni o je alakoso Ami irawo yi, eyi ntumosi pe ojo Tuesday ni ojo aseyori yin leyi to je pe nkan ti e ba dawole lawon asiko ti ko ba je awon asiko to buru ni yo ma bosi rere bakanna ti ko ba tako akosejaye yin toripe iyato wa laarin irawo ati akosejaye...

Awon onirawo yi je asiwaju lati orun wa saye leyiti o jasi pe kosi ibi ti won ba ba ara won ti won ki wa nipo olori nibe, won je oninurere ti o ma n g ero daadaa fun omonikeji re.

E je oninu lile eniyan ti ko fe iyanje laarin eniyan meji bakanna e ma nfe ki nkan tete ma wa si imuse fun yin eo kin ma n fi aaye gba ireti pipe ninu ise ati okan yin.

Ise bi jagunjagun, akorin ogun tabi ti ijala, alagbede, welder, surgeon etc. Je ise to ba irawo yin mu

Gbogbo ojo Tuesday je ojo aseyori yin
Gbogbo odun ti January 1 re ba je Tuesday je odun aseyori yin bakanna lo tun je adanu dukia, iku ati riri owo laarin awon alajosisepo, iyawo/oko, ana, tabi ogun jije fun yin.

Gbogbo ojo Friday je ojo ti eo ma tewo gba owo lati ara ise ti e ba da sile bakanna lati odo awon ara ita eo tun ma ri owo, asiko yi ni oro igbeyawo yo wa lori emi yin iyen ti ko ba je asiko naisi.
Odun ti January 1 re ba je Friday na je odun ti ao ma ri awon nkan wonyi na

NOTE:
Gbogbo awon die ti a menuba yi je awon nkan ti awon onirawo yi yo ma koju sugbon akosejaye enikookan won ni yo pin irinajo won lotooto...

Fun alaye lekunrere Lori irawo tabi akosejaye yin call/Whatsapp 08067589328

28/07/2021

*LATI MO NIPA IRAWO RE
*AKOSEJAYE RE
*GBOGBO ADOJUKO RE ATI
*ONA ABAYO SI AWON ISORO NA

Eni anfaani lati wa si office wa bakanna, e tun ni anfaani lati call tabi whatsapp wa pelu 08067589328...

Address

Ifedapo Lagbele, Elebolo Orita-merin Tioya, Ibadan
Apata Ibadan

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Stellium School of Astrology, Numerology & Palmistry posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share

Category