Happy Jumat Mubarak
ادب الدنيا IKO AYE
Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from ادب الدنيا IKO AYE, College & University, Ilorin, Abuja.
OSO GIDI TO DAJU Odindi eyele 2, afara oyin, ileke iyun, ewe omisinmisin onitakun, Sisere,, ao mu okan ninu eyele yi ao fi kan ori wa ao se adura si dada ao wa san mole lekan na koku, ao wa ju sinu agbada tati gbe kano, ao Jo pelu awon ewe yi, yato si ileke iyun yen ao lo ohun loto ni, ti abati jo tan alo kunna ao da ileke ti aloyen mo, ao wa polose, ao ti ran a*o funfun ni apo kan, ao ko ose yi sinure ao ja eyele to Ku ao ro ejere lori oaeyi ao wa ti ori re bonu oseyi ao so lenu aowa gbeko enu ona abawole loke fun 14 days kato ma buwe, pelu ofore
Gbolohun: Eyibieyi awo ataye baye, Atambata awo ode orun, Ogbonla sori jagajigi, Awon lodifa fun Orunmila ni igba ton ti ikole orunvbo wavsi Ikole aye, ode ibode orun ataye, onibode bere lowore wipe nibo lonlo, orunmila ni ounlo sode ayeni, onibode dalohun wipe oso tilo, aje tilo, Omo araye abi oju perekete ti kin je ki oniwagun wa, orunmila babinu pada s**o olodumare, olodumare ni kolowa eyin oku ila, afara oyin, oni kofi se IFA koma fiwe oni oso aye yio ma sin o, aje aye yio ma sin o, emi lagbaja moti wa eyin oku ila afara oyin adidi eyele motifi se ifa motifiwe loni, koso aye masin mi aje aye masin mi Alfa ati Woli aye e t c ki won ma sinmi, tori omisinminsin kin se be tire komadun. IKILO =AKO GBODO WO INU APO OSE YI RARA TAA FI LOTAN.
Owale fun tita iwo ti obanife si 08095509091
If you need money on ur client do the work I sure to my God you we cash out I sure
OGUN OMO YAHOO TODAJU
EWE LALI OWO TUN TUN KAN 1K OR 500 OGA AYE KAN IKE FUN FUN KAN OR AWO FUN FUN OSE DUDU
SISERE:::- Ao gun ewe lali na pomon Ose dudu ao wa fi owo yi tele Inu Ike na ao fi oga na si awo wa ko Ose na le Lori ao gbe pamon fun 7days leyin Ojo meje ao ma fi wa amagba owo nla
I sure to God if you need anything in this world jo's call me 08095509091 or WhatsApp
Click here to claim your Sponsored Listing.
Location
Category
Website
Address
Ilorin
Abuja
YES