02/05/2026
Victorious Montessori School
Here at Victorious, we develop tomorrow's frontliners, articulate and global citizens.
02/05/2026
18/04/2026
Cultural Day 2026.
18/02/2026
The in-house event at school today was a monumental success. Theme: Collaborating for Excellence in Education. Observe the excitement on the pupils' faces when parents visited classes. Parents assessed their wards' classroom activities for the past six weeks and were overjoyed. We are Victorious 💪.
05/10/2025
Iṣẹ́ AJÍMẸ́FUN, Iṣẹ́ àánú
Iṣẹ́ AJÍMẸ́FUN, Iṣẹ́ àṣejèrè
Iṣẹ́ AJÍMẸ́FUN, Iṣẹ́ atóríṣe.
Iṣẹ́ Ọ̀làjú, Iṣẹ́ àwọn Ọ̀jọ̀gbọ́n.
Iṣẹ́ Olùkọ́ wù mí yéye!
Olórí kíkú kì í ṣe é
Ọlọ́pọlọ pípé ní ṣiṣẹ́ ẹfun
Ọ̀mọ̀wé ènìyàn,
Ní í ṣiṣẹ́ Olùkọ́
Gbogbo olórí kíkú ọmọ
Ló ti d'ọlọ́pọlọ pípé ọmọ
Láti ipasẹ̀ Olùkọ́
Gbogbo akékọ̀ọ́ tí kò nímọ̀ rárá
Ṣe bí Olùkọ ló bu omi ọgbọ́n fún
wọn mu?
Tí wọ́n d'ẹni tó jáfáfá
Tí wọ́n d'ẹni tó lóye!
Tí wọ́n d'èèyàn àtàtà láwùjọ
Iṣẹ takuntakun ni Olùkọ́ ń se.
Iṣẹ́ Olùkọ́!
Iṣẹ́ Àṣelà
Iṣẹ́ Olùkọ́!
Iṣẹ́ Idùnnú ni
Òbí tó bá r'Ólùkọ́ fín,
Yóò dá ọmọ rẹ̀ kọ́ ní kọ̀rọ̀ yàrá.
Ẹ jẹ́ ká gb'ọ́lá fún gbogbo AJÍMẸ́FUN
Ẹ jẹ́ ká ṣè'bà fún gbogbo Olùkọ́ àwa.
Mo fẹ́ d'adájọ́
Mo fẹ́ di dókítà
Kò ṣe é f'ẹnu lásán jẹ́
Láìgba iwájú Olùkọ́ kọjá.
B'éèyàn yóò di Ààrẹ Orílẹ̀-èdè láyé,
Iwájú Olùkọ́ ni yóò ti bu omi ọgbọ́n mu.
Gbogbo ẹni di Gómìnà lónìí
Ti b'omi ọgbọ́n mu lọ́wọ́ AJÍMẸ́FUN.
ORIN
Àdúrà mẹ́ta ló yẹ Tísà mi; (2x)
Kó lówó, kó sì rérè jẹ.
K'ẹni ẹlẹ́ni má gbàṣe rẹ̀ ṣe.
Kó tún re ìlú òyìnbó ooooo.
Igi eléso jìngbìnnì; (2x)
Tísà ló so dókítà
ÈGBÈ: Igi eléso jìngbìnnì
Tísà ló so lọ́yà.
ÈGBÈ: Igi eléso jìngbìnnì
Tísà ló so báńkà.
ÈGBÈ:Igi eléso jìngbìnnì.
May God bless all our Teachers
Nigeria's 65th Anniversary of Independence
15/09/2025
Welcome Back to School
Victorious Montessori School resumes on 15 September 2025. We are excited to welcome our pupils back for another term of learning, growth and excellence.
For more information, contact us at:
📧 [email protected]
📞 08159271620, 08029020466
Enroll your child today for a safe, nurturing and academically sound environment.
Click here to claim your Sponsored Listing.
Location
Category
Telephone
Website
Address
Arigbajo
Abeokuta
Opening Hours
| Monday | 08:00 - 15:30 |
| Tuesday | 08:00 - 15:30 |
| Wednesday | 08:00 - 15:30 |
| Thursday | 08:00 - 15:30 |
| Friday | 08:00 - 13:30 |