Ìlú òwe àti iṣẹ̀dálẹ̀ yorùbá.
ilé ẹ̀kọ́ èdè àti àṣà yorùbá.
20/02/2026
ORO YORUBA TV is LIVE | TikTok Check out ORO YORUBA TV LIVE streams on TikTok! Watch, follow, and discover the latest content from ORO YORUBA TV.
15/10/2023
A kí gbogbo àwọn ènìyàn wa tuntun káàbọ̀ s'ílu òwe àti ìṣẹ̀dálẹ̀ yorùbá,,, Ẹ káàbọ̀ sà,,Ẹ káàbọ̀ mà. Àsìkò tí ẹ wọlé yìí yóò tu gbogbo ilé l'ára, Àmin àṣẹ èdùmàrè.
Evangelist Olayemi Oladimeji Ilori, Obafolahan Ganiyat, Temitope Amusa, Iya Segun Woli, Alabi Adebisi Rasheed Rashreed, Folusho Emmanuel, Zion Yosimi, Mujeeb Banuso, Morenike Eniola Motunrayo, Alfa Owolabi, Joseph Samuel Akintunde, Oluwatoyin Bamidele, Olori Omowunmi Omoniyi Olayiwo, Princess Afolake, Morienikeji Aborisade
22/05/2022
#
"""""""""""""""""""""""""""""
Mo kí t'ọmọdé t'àgbà ninú ilú òwe yi oo. A kú ìgbìyànjú ni gbogbo ìgbà àti nigbà gbogbo.
Ìbéèrè pàtàkì kan ni mo fẹ́ bi gbogbo Ọmọ yorùbá láti kọ́ ara wa l'ẹ́kọ si'i nipa àṣà àti ìṣe àwa yorùbá.
Ìró dídún ìlù kan lọ sọ bayìí ninú ayẹyẹ yorùbá,,,,
WÈRÈPÈ MÁ SO MỌ́,,,WÈRÈPÈ MÁ SO MỌ́,,,ÈYÍ TI O SO L'ÉṢI BABA ẸNIKAN Ò KÁ'A,,,WÈRÈPÈ MÁ SO MỌ́.
Ìbéèrè mi nìyí::---
""""""""""""""""""""""""""
1),,,,Irú ayẹyẹ wo ni yorùbá máa ńṣe tí wọ́n máa ńlu ilù yìí ???.
2),,,,Kini ohun tí wọ́n ni l'ọ́kàn tí wọ́n fi wípé kí wèrèpè ó má so mọ́???.
3),,,,Iṣẹ́ wo ni wèrèpè máa ńṣe,,,Ṣé onjẹ ni tàbí ohun ìṣeré lásán ni???.
Máaki (mark) wà fún ẹni tó bá gba ìbéèrè métẹ̀ẹ̀ta.
Tí ẹ bá gba ẹyọ kan (ikó ọgbọ̀n 30%).
Tí ẹ bá gba méjì (ìkó ọgọ́ta 60%).
Tí ẹ bá gba métẹ̀ẹ̀ta (ìkó ọgọ́run 100%).
Èdè àti àṣà yorùbá ò ni bàjẹ́ lásìkò tiwa oo,,,,,ẹ kú àf'ọmọniyànṣe o.