11/02/2026
EKO BIBELI YORUBA
use this link to join if you are interested
Follow this link to join my WhatsApp group: https://chat.whatsapp.com/LIV9N4QhPTZFlkdafJ4Hjv?mode=gi_t
Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Ẹkọ Bibeli NI Yoruba, Educational Research Center, Lagos.
11/02/2026
EKO BIBELI YORUBA
use this link to join if you are interested
Follow this link to join my WhatsApp group: https://chat.whatsapp.com/LIV9N4QhPTZFlkdafJ4Hjv?mode=gi_t
02/02/2026
IDANI LEKO OFE OLOJO MEJE NBO LONA
Kí ni ìtumọ̀ “ìmísí Ọlọ́run” gẹ́gẹ́ bí 2 Tímótì 3:16?
👉 Kí ló mú kí Bíbélì yàtọ̀ sí gbogbo ìwé míì tí ènìyàn kọ?
Ese bible 2 Timotiu 3:16; 2 Peteru 1:21
Ìbéèrè Ìjíròrò 3
Kí ló dé tí a fi sọ pé gbogbo Bíbélì ń tọ́ka sí Jésù Kristi?
👉 Ṣe o lè sọ àpẹẹrẹ kan láti Májẹ̀mú Àtijọ́ tàbí Májẹ̀mú Tuntun?
Ìbéèrè Ìjíròrò 2
Gẹ́gẹ́ bí Róòmù 15:4, kí ni àǹfààní Ìwé Mímọ́ nínú ìgbésí-ayé onígbàgbọ́?
Báwo ni Bíbélì ṣe ń fún wa ní ìkọ́ni, ìfaradà àti ìrètí?
Ìbéèrè Ìjíròrò 1
Kí ni ìtúmọ̀ Bíbélì sí ọ?
Ṣé o rí i gẹ́gẹ́ bí ìwé ìtàn nìkan, tàbí gẹ́gẹ́ bí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tí ń sọ̀rọ̀ sí ìgbésí-ayé wa lónìí?
10/01/2026
TANI LE BAWA SALAYE, GBOLO-UN ORO BIBELI YI
OKU NIGBATI O WA LAYE
TIMOTI KINNI 5:6
[6]Ṣugbọn ẹniti o ba fi ara rẹ̀ fun aiye jijẹ, o kú nigbati o wà lãye.
EBAWA FERAN RE, KI ESI BAWA PIN KAAKIRI, E SEUN
08/01/2026
AISAYA 45:2
Emi o lọ siwaju rẹ, emi o si sọ ibi wiwọ́ wọnni di titọ́: emi o fọ ilẹkùn idẹ wọnni tũtũ, emi o si ke ọjá-irin si meji.
08/01/2026
AISAYA 45:1
[1]BAYI ni Oluwa wi fun ẹni-ororo rẹ̀, fun Kirusi, ẹniti mo di ọwọ́ ọtún rẹ̀ mu, lati ṣẹ́gun awọn orilẹ-ède niwaju rẹ̀; emi o si tú amure ẹgbẹ awọn ọba, lati ṣi ilẹkùn mejeji niwaju rẹ̀, a ki yio si tì ẹnu-bode na;