OLU Osanyin Herbal and Natural Remedy

OLU Osanyin Herbal and Natural Remedy

Share

Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from OLU Osanyin Herbal and Natural Remedy, 3, Oluwo oje Close, isuti road, Egan, Igando, Lagos.

29/11/2021

ALWAYS BELIEVE IN YOURSELF.

12/11/2021

IWULO EWE ATI EGBO.
Olorun LoNi Ase.
Awa ko hun gbiyanju ni.

06/07/2021

ETO ADURA FUN ISEGUN WAHALA ATI IDAMU
A o gbawe funfun ojo meta,ni ojo keta,a o lora ose lux white kan,a o ra kahinkahin kan,a o ya ose ati kainkahin na si mimo pelu PS 24*7,leyin naa,a o wa ka PS 130*3,88*3,21*3,20*3,3*3,4*3, a o wa pe oruko oluwa yi si,ELI ELI ALOLA *3,sinu ose ATI kaihinkahin naa,a o wa gbadura si Dada, wipe ona ki di mo ojo ki o ma LA,ona ki di mo osupa ATI orun ki won ma yo,ki ona LA fun wa,
A o wa lo fi ose naa we ni odo ti o nsan,a o ma gbadura,a o si pe oruko oluwa naa nigba meta,ki o to ma we,ti o ba ti de odo,ki oto ma we.a o ju ose ATI kahinkahin naa si odo ti a ba ti setan,a o ni nu omi ara wa o,bakana o gbodo WO ehin ti o ba ti setan,ti a ba nwe .
Ikilo jowo sa fun ibalopo fun ose meta,leyin igba ti o ba ti se ETO naa.

24/12/2020

ESU IS NOT SATAN
Esu is an irunmole among many others, it is ignorantly been referred to as SATAN OR DEVIL but as a matter of fact, he is certainly not the devil of the New Testament in the Bible (Book of the Christian) nor SEITAN or Asitani as the Muslim cleric do call it.
Esu is primarily a special relations officer between heaven and earth, he can be referred to as the "inspector general " who reports regularly to olodumare on the deeds of the divinities and men, he checks and marks reports on the correctness of worship in general and sacrifices in particular.
In Yoruba traditional belief system, the babalawo (an ifa priest) usually hold the view that esu is created to be the right hand divinity to orunmila bara- agbonmiregun , Esu is ubiquitous because he must always be about his business of inspection, his portfolio includes, among other things, the inspection of worship and sacrifices, he works in collaboration with orunmila, he is the appover and bearer of sacrifices to heaven .
" owonrin a sogbe "
"ki esu gba "
Esu as a source of wealth to individual and especially a business man/woman
In odu ifa okanran meji, it is clearly stated that esu makes business activities to go well and helps about bringing more gain and achievement to someone day to day activities.,
Sowola Sowola sowola
Adifa fun elegbara
Ti yio fi Owo kan soso, se Owo la
Ti yio jere egberin oke
Nje ta lo fi Owo kan sowo la?
To jere egberin oke?
Elegbara lo fi Owo kan sowo la to si jere egberin oke "
This verse tells us how elegbara invested with little money and makes a lot of profit Which is applicable to us as individual and a business entrepreneur.
Esu is a great protector, esu can be worshiped for so many reasons, one of it is it's ability to protect his followers against enemy, this is why we have many families who worship esu and name there children after esu such as esubiyi, esuola, esudamilare, esulekan and so on
" Esu ko ibi kuro lori Awo "
Esu can be feed with many and different foods such as c**k, palm oil, goat, colanut, gin, bitter cola and so on and it has a lot of praise name based on it's character such as "Alakalu " meaning " He whose greatness is manifested all over the place"
It is also called elegbeje ado " the custodian of 700billions gourd" and each is used for different functions, that is why it is been praised as elegbeje ado in odu ifa "EJIOGBE "
Bo sa pamo
Ori re a ni oun ko sa pamo
Bi o rin ni ikoko eleda re a ni oun ko rin ni ikoko
Adifa fun alangajiga ti yio fi ise baba re sile
Ti yio ma se ise baba o ni baba
Nje esu a gbe wa, elegbeje ado
Alangajiga, odara a gbe wa o
Elegbeje ado, alangajiga
This simply explained how esu uses it's gourd to bless his followers.

Esu is a benefactor of a community for instance most esu residing in Orita meta send back evil or calamity that might likely befall such community, how come some people ignorantly tagged such dieties as been devilish.
It is high time we wake up from our slumber and orientate our different communities about what ESU as a dieties is up to.


From : Oluwo Fasola Faniyi babatunde

24/10/2020

OGUN AYETA
*Ewe tangiri
*Ewe rinrin
*Igba olomori
*Rice
Ao gbo ewe tangiri na,
Ao da si inu igba
Ao da rice na si ni iwanba tole se jina ,
Ao ko ewe rinrin na si, igba na ni ao fi se jina. Fun iwo ti koba ye.
Pe +23426661843

07/04/2020

IBA EYIN AGBAGBA .OANI SE LASAN, OA NI SE ASETI, INU WA ADUN OKAN WA ABA LE.
IKU OJIJI ONI PAWA TOMOTOMO.
-OSANYIN ISEGUN.

12/02/2020

OGUN FUN GBOGBO KOKORO INU EJE.
Bi eeyan ba we tan, ti gbogbo ara ba n ja je tabi ti ara ba n ja je ni
gbogbo igba tabi ki kokoro wa lara wa gegebi kuruna tabi kokoro
eyikeyi. iwadi ijinle awon agbalagba fi ye wa wipe kokoro inu eje lo
n fa awon inkan wonyi. Otito Oogun re ni eleyi...
Ao wa Egbo Igi ti Yourba n pe ni Akogun, ao gun po ti yio kunna
daada, ao da sinu igo tabi ike, ao da omi osan wewe to po die si.
Lilo Re: Ao ma mu niwon sibi imuko laaro ati lale leyin ounje. Eni ti
o ba ni arun (Ulcer) ko gbudo lo omi osan wewe, ki eni na lo
omi lasan.

05/02/2020

Awebi Awon Agba.
adaripon kan eru alamo epo obo ao gun papomo ose ao ko sinu igba onikoko olomori kogbodo kanle mo ao wafi owo eyo tikoluju te ifa eji ogbe lelori ao fi abere gun ni eji ogbe lori ni arin ao mafi we tabi ti ara enia kobaya ki afun we yio gbadun.

07/01/2020

OGUN AFATO (S***M )

EYIN ADIE OROR (10)AO MISSED RE MON SCHNAPP AOFI IYO OBE DIE SI AOMAN YO MUN NI OWURO ATI ALE.

Photos from OLU Osanyin Herbal and Natural Remedy's post 03/01/2020

S*X POSITIONS THAT CAN BREAK THE P***S.
OUR PAGE FOR MORE HEALTH TIPS AND HOME
REMEDIES
It is indeed exciting to adopt to different s*x positions when
having s*x. Among the many health benefits of s*xual in*******se
,changing s*x positions helps in counting it as a firm of exercise.
However, there are certain s*x positions that if care is not taken
,can cause pe**le fracture or let the p***s break . Among the
numerous s*x positions in the world. COWGIRL (woman on top)
takes the lead when it comes to pe**le fracture. Other s*x
positions can lead the p***s in hitting on the bone area of the
woman as its erected it can cause fracture.
A pe**le fracture is a rupture in the two areas of the p***s
responsible for er****ons. The corpora cavernosa and the pe**le
sheath.
Because the injury can cause long-lasting damage to a mans
s*xual and urinary function. It is important to seek emergency
attention.
.
- bleeding from the p***s
- experiencing dark coloured bruising to the p***s
- having trouble urinating
- hearing a cracking or poping sound
- losing an er****on suddenly
- pain that varies from minimal to severe.
The p***s has an area of spongy like tissue called the corpus
cavernosa. When a man has an er****on ,the p***s is erect . A
flaccid p***s does not typically fracture because the corpus
cavernosa is not as enlarged as when the p***s is erect.
The injury usually happens when a man is thrusting against the
p***c bone or the perineum, which can cause the corpus
cavernosa to snap break.
However a pe**le fracture has also been known to occur in the
following circumstances.
- rolling over in the bed onto an erect p***s
- hitting an erect p***s on something such as a door frame or
furniture.
- falling onto an erect p***s.
The faster a man can see a doctor and have the fracture treated,
the more likely he is to experience a full recovery. While most
men will be able to go home after the procedure, a we can
advise to refrain from s*xual activities for atleast 1month.

health is our PRIORITY

03/01/2020

ATUDE ASINA Todaju
Ewe ejirin, ewe lapa ff ati pupa ewe akoko, ao fi Omi gbogbo awon ewe wonyi, ao gbe si eri (dew) ti obadi oru ni agokan aowe pelu ose.
Ose niyi- epo obo, imi ojo aolopo mo ose dudu... Odaju

31/12/2019

HAPPY NEW YEAR, OUR YEAR OF PROSPERITY

Want your school to be the top-listed School/college in Lagos?

Click here to claim your Sponsored Listing.

Location

Culinary Team

Attire

Telephone

Website

Address

3, Oluwo Oje Close, Isuti Road, Egan, Igando
Lagos