01/10/2025
A ku ajodun Ominira Naijiria
Translators. Interpreters. Yoruba Language Tutors. Yoruba Specialists e.t.c https://youtu.be/ZlvW5pcmMOk
01/10/2025
A ku ajodun Ominira Naijiria
A ku ajodun ominira ooo
Iwa rere leso eniyan.
Iwa ati eso 🤔
Tani o le se alaye eyi ni knikun fun wa? fans Yoruba Language Experts
12/11/2024
Anfaani kan wa fun awa ti a ba fe se, tabi mo nipa idanwo IELTS:
Ni Ojobo, 14th November ni ago mejo ale. E je ka darapo lati ni imo kun imo.
If you want to write the IELTS test or you know someone who wants to. Join this exclusive programme this Thursday at 8pm for a successful journey.
05/10/2024
Oni ni Ojo imoyi awon Oluko kari aye
Nje Oluko kan wa ti o fe gboriyin fun julo?
E daruko won nibi!
Gbogbo Oluko patapata, a ki yin, e seun gan.
E ku se, e ku suuru, e ku afomoniyanse
Oluko se pupo loro wa!
Happy Teachers' Day!
_________________________________
Your hard work, especially in preserving our culture and language, inspires generations. Thank you for nurturing minds and hearts with wisdom and love. E seun!
05/10/2024
Oni ni Ojo imoyi awon Oluko kari aye
Nje Oluko kan wa ti o fe gboriyin fun julo?
E daruko won nibi!
Gbogbo Oluko patapata, a ki yin, e seun gan.
E ku se, e ku suuru, e ku afomoniyanse
Oluko se pupo loro wa!
Happy Teachers' Day!
Yoruba Language Experts
TEACHERS REGISTRATION COUNCIL OF NIGERIA (TRCN) INFO
01/10/2024
A ku odun ominira, gbogbo omo Naijiriya 🇳🇬
E ba wa gbe orin yi ti e ba mo:😊
Ki eni kokan da si pelu gbolohun kookan. Oya, e je ka lo!💪
Lubulubu tani o r'oja b'o ba d'ale?...
E te idahun yin si abe abala to wu yin nisale yii.
19/09/2024
Did you know?
Nje e le gbe ni ilu Eko?
E dahun pelu alaye. 😊
| Monday | 09:00 - 17:00 |
| Tuesday | 09:00 - 17:00 |
| Wednesday | 09:00 - 17:00 |
| Thursday | 09:00 - 17:00 |
| Friday | 09:00 - 17:00 |