Yoruba Language Experts

Yoruba Language Experts Translators. Interpreters. Yoruba Language Tutors. Yoruba Specialists e.t.c https://youtu.be/ZlvW5pcmMOk

A ku ajodun Ominira Naijiria
01/10/2025

A ku ajodun Ominira Naijiria

01/10/2025

A ku ajodun ominira ooo

28/11/2024

Iwa rere leso eniyan.
Iwa ati eso πŸ€”

Tani o le se alaye eyi ni knikun fun wa? fans Yoruba Language Experts

Anfaani kan wa fun awa ti a ba fe se, tabi mo nipa idanwo IELTS:Ni Ojobo, 14th November ni ago mejo ale. E je ka darapo ...
12/11/2024

Anfaani kan wa fun awa ti a ba fe se, tabi mo nipa idanwo IELTS:

Ni Ojobo, 14th November ni ago mejo ale. E je ka darapo lati ni imo kun imo.

If you want to write the IELTS test or you know someone who wants to. Join this exclusive programme this Thursday at 8pm for a successful journey.

Oni ni Ojo imoyi awon Oluko kari ayeNje Oluko kan wa ti o fe gboriyin fun julo?E daruko won nibi! Gbogbo Oluko patapata,...
05/10/2024

Oni ni Ojo imoyi awon Oluko kari aye
Nje Oluko kan wa ti o fe gboriyin fun julo?
E daruko won nibi!

Gbogbo Oluko patapata, a ki yin, e seun gan.
E ku se, e ku suuru, e ku afomoniyanse
Oluko se pupo loro wa!

Happy Teachers' Day!
_________________________________

Your hard work, especially in preserving our culture and language, inspires generations. Thank you for nurturing minds and hearts with wisdom and love. E seun!

Oni ni Ojo imoyi awon Oluko kari ayeNje Oluko kan wa ti o fe gboriyin fun julo?E daruko won nibi! Gbogbo Oluko patapata,...
05/10/2024

Oni ni Ojo imoyi awon Oluko kari aye
Nje Oluko kan wa ti o fe gboriyin fun julo?
E daruko won nibi!

Gbogbo Oluko patapata, a ki yin, e seun gan.
E ku se, e ku suuru, e ku afomoniyanse
Oluko se pupo loro wa!

Happy Teachers' Day!
Yoruba Language Experts
TEACHERS REGISTRATION COUNCIL OF NIGERIA (TRCN) INFO

A ku odun ominira, gbogbo omo Naijiriya πŸ‡³πŸ‡¬
01/10/2024

A ku odun ominira, gbogbo omo Naijiriya πŸ‡³πŸ‡¬

20/09/2024

E ba wa gbe orin yi ti e ba mo:😊

Ki eni kokan da si pelu gbolohun kookan. Oya, e je ka lo!πŸ’ͺ

Lubulubu tani o r'oja b'o ba d'ale?...
E te idahun yin si abe abala to wu yin nisale yii.

Did you know?
19/09/2024

Did you know?

18/09/2024

Nje e le gbe ni ilu Eko?

E dahun pelu alaye. 😊

Address

31 Ogunjobi Street Fadeyi
Lagos
100212

Opening Hours

Monday 09:00 - 17:00
Tuesday 09:00 - 17:00
Wednesday 09:00 - 17:00
Thursday 09:00 - 17:00
Friday 09:00 - 17:00

Telephone

+2348034198012

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Yoruba Language Experts posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The School

Send a message to Yoruba Language Experts:

Shortcuts

Share