SAARA ITUSILE NINU IGBEKUN AIYE
SAARA ATI ADUA
Saara ati Adua yio mu iyipada rere ba aiye eda, gbiyanju kio maṣe saara lori awọn adua rẹ
SAARA AṢINA TODAJU
SAARA ITUSILE NINU IDE AWỌN ỌTA
Plz share for others like and comment
21/05/2024
SAARA ATI ADUA
Saara yi ṣiṣe fun Iṣẹgun awọn ọta ati bibọ kuro ninu igbekun awọn ọta pẹlu ẹlẹmi okunkun, o tun sise fun eniti o banmu amubọ oore tabi amubọ iṣẹ, gbìyànjú rẹ wo, wa dupe fun Olohun
Ao ra akukọ adiyẹ pupa ẹyọkan (1)
Epo pupa idi meje (7)
Obi pupa meje (7)
Owo one hundred Naira meje (7)
Igbale odidi Meji (2)
Aṣọ pupa ọpa meji (2)
SISERE:- Ao ṣe eyikeyi adua Iṣẹgun tio ba rọwa lorun fun ọjọ mẹta, meje tabi mẹsan leyin adua na ao lọra gbogbo inkan saara yi, ao wa daniyan Iṣẹgun ọta tabi bibọ kurọ ninu igbekun ọta si saara yi, leyin na ao lọ gbe gbogbo saara na fun mọla obinrin Arugbo tabi afọju obinrin, pẹlu aṣẹ ati agbara Olohun wa ri iyipada daada pẹlu Iṣẹgun laipe tio ba le gbiyanju rẹ.
Fun iwọ tio ba fẹ gbiyanju iṣẹ saara yi tio si fe tete ri gbigba adua lorie bami share re fun eyan mẹta (share for others)
GBOGBO OGUN ATI IGBEKUN AIYE RẸ YIO DI OHUN IGBAGBE PELU AṢẸ ỌLỌHUN SE AMIN ADUA YI AMIN
21/05/2024
SAARA ATI ADUA
SAARA LATI BỌ LỌWỌ ỌTA ATI LATI TAN INA IRAWỌ AIYE RẸ TI OTI KU PADA
Ao ra abo adie dudu eyọ kan
Abela funfun odidi idi kan
Owo ₦50 eyọkan abi mẹrin
SISERẸ:- Ao gba awẹ ọjọkan pelu ọpọlọpọ adua ao wa se saara yi ki orun ọjọ na to wọle abi kia se ni ọjọ keji nigbati orun yọ, ao lọ gbẹ fun onibara, ọkunrin yio gbe fun ọkunrin beni ọbinrin yio gbẹ fun obinrin
Fun orisirisi saara ati adua join group (SAARA ATI ADUA) ABI (ADURA MI GBA) tabi kio pe awon numbers wonyi fun ekunrere alaye 08025821805, 08143187737
share for others
OLOHUN YIO GBA OGO RE PADA FUN E LOWO OTA RE AMIN
20/05/2024
SAARA FUN ARANSE OLOHUN ATI KI CONTRACT TI ENIYAN NWA LE TO EYAN LOWO NI KIAKIA
Opolopo ireke
Opolopo ofio
Opolopo dabidun
SISERE:- Ao ko gbogbo esoyi si iwaju wa, ao wa ka isaajaha 101 dele, Ao pin esoyi fun awon omode abi fun awon onibara pelu ase Olohun ao ri gbigba adua
AKIYESI:- Fun eniti komo isaajaha ki ase adua aranse eyiti a mo si, ki asilo fi se saara
Ao se saara yi ni emerin losu
Fun orisirisi saara ati adua join group
SAARA ATI ADUA abi ADURA MI GBA
Bere fun iwe saara ati adua abi kio pe awon numbers wonyi fun ekunrere alaye
08025821805, 08143187737
GBOGBOWA LAO SE ASEYORI PELU ASE OLOHUN AMIN
20/05/2024
SAARA ATI ADUA
SAARA FUN ẸNITI OUNWA ISẸ ATI AṢINA OORE TUNTUN FUN GBIGBA CONTRACT
Ao wa ẹwa oloyin ti yio kun inu fila eyiti ati wọri
Obi pupa ẹyọ mesan (9)
Owo ₦200 ẹyọkan (1)
Ao wa se adua si daada ni irọle ijọ jimọh friday lẹyin iru asri di igbati irun ishai yio wọle 4pm to 7pm asiko re niyẹn.
Ao gbe saara yi fun onibara okunrin ti o we lawani lori ijoko pelu ase Ọlọhun ti o ba gbiyanju saara yi wa dupẹ fun Allah o daju pupọ
Fun orisirisi saara ati adua join group SAARA ATI ADUA abi ADURA MI GBA ni ori facebook
Abi kio bere fun IWE SAARA ATI ADUA.
pe awon numbers wọnyi fun ẹkunrẹrẹ alaye
08025821805, 08143187737.
20/05/2024
IWULO AGBON FUN SAARA
FUN ITUSILE LOWO AWON EMI OKUNKUN ATI LATI GBA OGO WA PADA LOWO AWON OTA
Ao bere awe olojo meta pelu adua, Ti awe yi baku eyokan ti yio fi pari ao lo ra Agbon nla meta toni omi ninu daada ao fi sun moju ojo na, Ao fi eyokan si egbe ori ao fi ekeji si egbe ikun ao fi iketa si egbe ese lori ibusun wa, Ao toro Inkan ti afe ki ato sun. Ti aba waji ao niti ba enikankan soro ao wa ko agbon meteta si iwaju wa ao se adua si bayi wipe gbogbo ogo mi towa lowo otami ki Olohun bami gba pada gbogbo ibiti ota bade oore ayomi mo ki Olohun tumi sile tori kosi eniti o mo bi omi se de inu agbon leyin Olohun bi Oore ayomi se ma tomi lowo komaye awon ota mi, ao se awon adua miran si awon agbon yi, leyin na ao fo awon agbon yen, Ao da omi inure sinu ike iwe ao bu iyo die si, ao lofi omi agbon na san arawa, ao wa yo agbon yen sinu ike funfun kan, Ao wa ra sugar pali kan ao yo meta si inu ike ti agbon yen wa fun jije.
Ao bu omi die si leyin ti ati ge agbon yen si kekeke ao pin fun awon eyan ao tun wase adua si sugar toku ao pin iyen fun awon omo wewe.
Iseyi dara pupo debi wipe gbogbo Inkan ti aba fi bere lori itusile ni yio ribe pelu ase Olohun gbiyanju re wa dupe fun Allah
AKIYESI PATAKI:- Ao jeki adua sise po daada fun wa nigba ti abanse adua yi lowo dadaa
ki a si jina si awon Inkan ti Olohun o fe
Fun orisirisi awon Saara join awon group yi
SAARA ATI ADUA
ADURA MI GBA
ADURA NI IDA MUMINI
Abi kio bere fun iwe SAARA ATI ADUA.
pe awon numbers won yi fun ekunrere alaye 08025821805, 08143187737
Share for others
OTA O NI GBA OGO AYEWA LOWO WA AMIN
Click here to claim your Sponsored Listing.