20/05/2024
IWULO AGBON FUN SAARA
FUN ITUSILE LOWO AWON EMI OKUNKUN ATI LATI GBA OGO WA PADA LOWO AWON OTA
Ao bere awe olojo meta pelu adua, Ti awe yi baku eyokan ti yio fi pari ao lo ra Agbon nla meta toni omi ninu daada ao fi sun moju ojo na, Ao fi eyokan si egbe ori ao fi ekeji si egbe ikun ao fi iketa si egbe ese lori ibusun wa, Ao toro Inkan ti afe ki ato sun. Ti aba waji ao niti ba enikankan soro ao wa ko agbon meteta si iwaju wa ao se adua si bayi wipe gbogbo ogo mi towa lowo otami ki Olohun bami gba pada gbogbo ibiti ota bade oore ayomi mo ki Olohun tumi sile tori kosi eniti o mo bi omi se de inu agbon leyin Olohun bi Oore ayomi se ma tomi lowo komaye awon ota mi, ao se awon adua miran si awon agbon yi, leyin na ao fo awon agbon yen, Ao da omi inure sinu ike iwe ao bu iyo die si, ao lofi omi agbon na san arawa, ao wa yo agbon yen sinu ike funfun kan, Ao wa ra sugar pali kan ao yo meta si inu ike ti agbon yen wa fun jije.
Ao bu omi die si leyin ti ati ge agbon yen si kekeke ao pin fun awon eyan ao tun wase adua si sugar toku ao pin iyen fun awon omo wewe.
Iseyi dara pupo debi wipe gbogbo Inkan ti aba fi bere lori itusile ni yio ribe pelu ase Olohun gbiyanju re wa dupe fun Allah
AKIYESI PATAKI:- Ao jeki adua sise po daada fun wa nigba ti abanse adua yi lowo dadaa
ki a si jina si awon Inkan ti Olohun o fe
Fun orisirisi awon Saara join awon group yi
SAARA ATI ADUA
ADURA MI GBA
ADURA NI IDA MUMINI
Abi kio bere fun iwe SAARA ATI ADUA.
pe awon numbers won yi fun ekunrere alaye 08025821805, 08143187737
Share for others
OTA O NI GBA OGO AYEWA LOWO WA AMIN