Celebrating my 4th year on Facebook. Thank you for your continuing support. I could never have made it without you. 🙏🤗🎉
Ìdàgbàsókè Àti Ìgbéga Èdè Yorùbá
TRY AND SEE!!!
TI WA LÀṢÀ
KÍN NI ÀWỌN YORÙBÁ Ń PÈ NÍ ÀLỌ̀?
ORÍSÌÍ ÀLỌ́ MÉLÒÓ LÓ WÀ?
DÁRÚKỌ WỌN!
PA ÀWỌN ÒWE TÓ NÍ Í ṢÉ PẸ̀LÚ KÒKÓ ÀTI Ọ̀KẸ́RẸ́
ẸYẸ Ò DÉDÉ BÀ LÓRÙLÉ, Ọ̀RỌ̀ LẸYẸ Ń GBỌ́...
04/08/2024
MÁ DÙRÓ
MÁ NÀ GẸ̀RẸ̀
MÁ DÚRÓ DÌ MÁA BẸ̀RẸ̀ NÍ ŃLÁ
ÀWỌN TÓ DÚRÓ BẸ́Ẹ̀ RÍ
KÓ RÍBI BÁYỌ̀ NÍGBẸ̀YÍN
ÀÌNÍ NIRÚ WỌN PADÀ BÁ KÚ
YÁRA TARA ṢÁṢÀ
ṢE KÁNKÁN
KỌ́JỌ́ Ó TỌ LỌ
DÌDE NÍLẸ́
PAKÍ MỌ́RA
KÓ O BẸ̀RẸ̀ NÍBI KÉKERÉ
KÒ O LÉ DI NLÁ NÍ KẸ̀RẸ̀KẸ̀RẸ̀
ỌJỌ́ NÍÍ PẸ́
ÌPÀDÉ KÌÍ JÌNNÀ
KÁ TÓ SẸ́JÚ PẸ́Ẹ́
Ẹ̀KỌ TI SÓJÚ MÍMÚ
Ọ̀RẸ́, KÁRÒYÉ TÌ
KÓ O WÁ NǸKAN ṢE
© LOVECHILD YORÙBÁ PRECEPTOR AND TRANSLATOR (ṢEUN AKÍNWÁLÉ)
APÁ LARÁ
ÈJÌKÁ NIYÈKAN
BÍ A KÒ RẸ́NI FẸ̀YÌN TÌ
BÍ Ọ̀LẸ LÀÁ RÍ
BÍ A KÒ RẸ́NI GBẸ́KẸ̀LÉ
KÁ TẸRA MỌ́ṢẸ́ ẸNI
ÌYÁ RẸ LÈ LÓWÓ LỌ́WỌ́
KÍ BÀBÁ RẸ LẸ́SIN LÉÈÈKÀN
BÍ O BÁ GBÓJÚ LÉ WỌN
O TẸ́ TÁN NI MO SỌ FÚN Ọ..
Ẹ̀KỌ́ INÚ EWÌ YÌÍ NI PÉ........
BÍ KÒ BÁ SÍ OLÙRÀNLỌ́WỌ́ FÚN Ọ
TÈTÈ WÁ NǸKAN ṢE KÍ ỌJỌ́ TÓ LỌ....
NÍTORÍ PÉ, ÀTẸ́LẸWỌ́ ẸNI KÌÍ TAN NI JẸ
Click here to claim your Sponsored Listing.