24/07/2026
GBAJUMỌ NÍ MI LÁWÙJỌ
Mo gbajúmọ̀ láwùjo àwọn oúnjẹ bẹẹ ni orisirisi oúnjẹ là lè mú jáde latara mi.
IRÚ ÀWỌN OÚNJẸ WO LALE MÚ JÁDE LATARA Ẹ̀GẸ́
ÀṢÀ ÀTI ÌṢE YORÙBÁ
24/07/2026
GBAJUMỌ NÍ MI LÁWÙJỌ
Mo gbajúmọ̀ láwùjo àwọn oúnjẹ bẹẹ ni orisirisi oúnjẹ là lè mú jáde latara mi.
IRÚ ÀWỌN OÚNJẸ WO LALE MÚ JÁDE LATARA Ẹ̀GẸ́
KÁ KÓ ẸYIN SỌ́WỌ́ Ọ̀TÚN, KÁ KÓ ẸYÌN SỌ́WỌ́ ÒSÌ, KÁ WÁ FI Ẹ̀YÌN RÌN LÁTI ÌHÍN DÉ ÌSẸ́YÌN.
ẸNI TÍ Ò NÍ YINNI KÒ NÍ YINNI.
Má ṣe fi dúdú pé funfun torí bí irọ́ bá lọ lógún Ọdún
Ọjọ́ kan ṣoṣo ni òdodo á báà.
Kí Ilẹ̀ tó pòsìkà
Ohun tó dára áti bàjẹ́
MO SOORE KÒ GBÈMÍ
Á JẸ́ PÉ Ó LỌ́WỌ́ KAN ÌKÀ NÍNÚ
RERE LOLÚWA FÍ SẸ̀SAN ORE.
Ẹ JẸ́ KÁ ṢE RERE TORÍ ỌMỌ.
ÀSE GBÉ KAN KÒ SÍ LÁYÉ
ÀSE PAMỌ́ LÓWÀ
KÓ TÓ SÈKÀ
RÁNTÍ Ẹ̀SAN.
11/07/2026
One of our fallen heroes in the Oriire kidnap rescue mission: Lt. Issac. Rest in peace gallant officer.
I salute you and pray that your family is comforted and adequately compensated by an appreciative country.
10/07/2026
A dúpẹ́ lọwọ Ọlọ́run.
Wọn tí rí àwọn ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ àti Olùkọ́ tí wọn wá lakata àwọn ajinigbe ni ìjọba ìbílẹ̀ orire nipinle Ọ̀YỌ́ gba padà
Yorùbá ni bí iná bá ń jó lóko?
Ẹ parí owe yìí.
Ayé wa á tòrò títí dọjọ́ alẹ́ wa