Tewe Tegbo

Tewe Tegbo

Share

com for any kind of spiritual solution for your problem

23/05/2025
27/06/2023

OPOLO NLA 3 ATARE NLA 3 AIDAN 3 AJOPO AMAFI EPO PUPA LO LALALE .TI ABATILO ANIJADE NIJOYEN MON

24/07/2017

isawuru eyokan odindi atare kan ajopo afisin gbere 3 somo leti otun 3 somo leti osi .........tiwon banpewa laburu anigbo

29/04/2017

Ewe ewuro ojoo epo obo gbigbe ogede omini meta.agun lototo atun wagunpo mon ose dudu awa mafiwe ki atomalo so shop wa .........Awure itaja todaju niyen.mafun yin ni iparare tobaya

14/05/2016

idena romonlowo romonlese odu opolo nla kan afi ose dudu no gbogbo arare ajopo pelu odindi atare afisin gbere meta meta si orikerike arawa .odaju

05/12/2014

Ekale eyin temi emabinu simi kobaleda loje kinpe.sugbon lati olalo mabere sinifi asiri se omo araye lore.pelu ogo olohun

22/11/2014

Eku irole eyin eyan mi.tewe tegbo wa fun iwuio ati itoju ara lati mafi san fani fun omo araye.emabami kalo

22/11/2014

Eku irole eyin eyan mi.tewe tegbo wa fun iwulo arawa latifi makowa bi ase malo ewe ati egbo fun itoju arawa....gbogbo eyi tabanso kaye mafibiwa o amin

Want your school to be the top-listed School/college in Ibadan?

Click here to claim your Sponsored Listing.

Location

Category

Telephone

Website

Address


Salvation Army Road Ekotedo Ibadan
Ibadan