14/05/2026
Ìdìbò 2027 ń bọ̀, òṣèlú sì ti bẹ̀rẹ̀ sí í gbóná. Bí o bá ní ànfàní láti pàdé òṣèlú kankan, béèrè lọ́wọ́ wọn ìbéèrè pàtàkì yìí:
“Kí ni ètò yín láti mú kí ẹ̀kọ́ sáyẹ́ǹsì àti ìmọ̀ ẹ̀rọ wà ní èdè abínibí wa?”
Èyí jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọ̀nà tó dájú jù lọ láti fún ìran òní àti ti ọjọ́ ọ̀la ní agbára.
Election 2027 is coming, and politics is already heating up. If you get the chance to meet any politician, ask them one crucial question:
“What is your plan to make science and technology education available in our mother tongues?”
That is one of the surest ways to empower both the present and future generations.
Tag any southwest politician you know