Oro re ooo,
E gbo ooo
Ile Eko Awon Omo Irumole
Ori eni lawure eni
Ògún was one of the messengers of olódùmarè known as òrìsà, someone with uncommon power and intelligence. Ògún and his other òrìsàs made into deities, irúnmọlẹ̀ by people. There's nothing bad in making reference to their good deeds while they were alive. There were millions of people who had outperformed those òrìsàs in terms of medicine, security, technology, power supply, spirituality, economy, philanthropy, education and so on, and not made deities, and there are far more people greater than those, who are still alive.
Kindly press like and follow for more if this is educating enough.
27/04/2026
Nígbà tí àwọn kan rí Ìkànnì Àrọ̀nì Èdè . Wọ́n rò wípé ààlọ́ àpamọ̀ àti àpagbé ni mò npa níbí .
Wọ́n ti lérò wípé Ọyá di omi , Ọbà di odò , Ṣàngó wọlẹ̀ ní kòso ni mo fẹ́ẹ́ máa báwọn sọ .
Òbírí layé yíyí ló nyí , ayé ti kúrò ní ayé Ìgbàgbọ́ , ayé ti di ìyẹ́ ìmọ̀ . Belief is a doubt and knowledge is power.
Ọmọ aráyé fẹ́ràn irọ́ tó bẹ́ẹ̀ gẹ́ẹ , gbogbo àwọn tí wọn ò ní Agbada ìjóògùn ní Ilé wọn nfi owọ́ sòyà fún mi wípé Òògùn ọfẹ́ wà . Àwọn tí wọn ò mọ ìwúlò oun tí wọ́n npè ní Ataare .
Mo sì rí ìmọ̀ràn ẹ̀yin olólùfẹ́ ìkànnì yí tí ẹ sọ wípé kí nmá sọ ọ̀rọ̀ nípa Òògùn mọ́ . Ó dà bí ẹni wípé ẹ̀ nsìmí gbọ́ .
Miò sọ wípé kò sí òògùn , ewe nbẹ nílẹ̀ Yorùbá tí kò jẹun .
Àmọ́ gbogbo ẹnu ni mo fi sọọ́, kò sí Òògùn owó , Ìbọn , Egbé, ọfẹ àti àfẹ́ẹ̀rí . Baba nlá irọ́ gbáà ni .
This is age of Knowing not age of believing. The new generation must think differently to evolve and meet the world standard.
Akiyesi nla gba lodeyi ooo,
Gbogbo omo Yoruba e ma sun ooo,
O nbo o nbo, awon la de e de ooo.
Olodumare a gba wa ooo.
27/04/2026
They advised us to go back to school but deep down, their intention was to ruin our career to enable them survive the pressure we were giving them- Shanko Rashidi referred to Pasuma's song where he advised him and his upcoming colleagues to go back to school.
He alleges that senior colleagues then paid promoters to stop promoting them just bcos we young artistes then were giving them pressure, especially me.
We listened to them when they advised us to go back to school without knowing their advice was meant to ruin our career.
I've just reached 100 followers! Thank you for continuing support. I could never have made it without each one of you. 🙏🤗🎉
I've reached a significant milestone of 100 followers. I appreciate your ongoing support. I couldn't have done it without each of you. 🙏🤗🎉
Click here to claim your Sponsored Listing.
Location
Category
Website
Address
Ibadan
200213