Olorun IPE Prayer GROUP

Olorun IPE Prayer GROUP Adura lo ngba agbara ko Igbagbo,ireti,ileri ti ki ye

23/05/2022

Ma f'aiye han mi lailai.iwo l'oba to Fi mi han awon enia.ma f'aiye han mi lailai.

08/04/2022

Gbogbo eni ti abi ninu obinrin tabi ti a Fi obe gbe jade ninu obinrin,to oun o ra ogo iboji fun m mi tomo-tomo, olorun bami Fi se esin,aiyeraye.

15/05/2020

Olorun oooo
My gbogbo ala RERE mi se ni kiakia loruko Jesu.

15/05/2020

GBOGBO OHUN TI AIYE FI OKUNKUN BAJE/GBALO LAIYE MI, OLORUN FI IMOLE AROJAH RE BA MI SE ATUNSE E. LORUKO JESU.

07/11/2019

GBOGBO eni so Ara e di lyalode lori emi ati awon omo mi,olorun BAMI si lowo ise

21/08/2019

AGINJU ISORO LAIYE,eni ba pada seyin ko sora ewu MBE.
Olorun di mi mu,ki n ma ba subu.

09/05/2019

Gbogbo emi airi, eyi to nparada SI eranko kan tabi ekeji,lati fi ara ni mi, MO palase loruko Jesu,EMA subu sowo ida,bi e ti nsubu sowo ida be na ni ki EMA segbe loruko Jesu

MO NA OWO SI PEPE,EMI MIMO IRE MI DA, MO NA OWO SI PEPE     OLORUN fi ire mi le mi lowo.
09/05/2019

MO NA OWO SI PEPE,EMI MIMO IRE MI DA, MO NA OWO SI PEPE
OLORUN fi ire mi le mi lowo.

05/01/2019

Ninu odun 2019 yi, olorun fi aye GBA mi,olorun so agbegbe mi di NLA,loruko Jesu.

Address

Oridanisi Estate
Atan Ota

Telephone

+2348097036955

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Olorun IPE Prayer GROUP posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share

Category