Adun Ede yoruba

Adun Ede yoruba Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Adun Ede yoruba, Language school, Akute, Akute-Oja.

"Awọ̀n amọ́na  l”ọ́dún eṣí, wọn o kìí ṣe àmọ̀nà mọ̀ l”ọ́dún yìí."
26/08/2026

"Awọ̀n amọ́na l”ọ́dún eṣí, wọn o kìí ṣe àmọ̀nà mọ̀ l”ọ́dún yìí."

"Wọ́n ní kí a sọ fún wọn wípé, a dá wọ̀n mọ̀, kí wọn má pe àfin ní òyìnbó fún wa."
25/08/2026

"Wọ́n ní kí a sọ fún wọn wípé, a dá wọ̀n mọ̀, kí wọn má pe àfin ní òyìnbó fún wa."

"Akìregbé nì yóò juwé ìfòkùnsí, akìká nì yóò juwé ibi tí ẹkùn yóò ti gún ohùn."
24/08/2026

"Akìregbé nì yóò juwé ìfòkùnsí, akìká nì yóò juwé ibi tí ẹkùn yóò ti gún ohùn."

BI OMO KO BA JO SOKOTO
23/08/2026

BI OMO KO BA JO SOKOTO

"Irun ori ko ni kun ki a ba ejo(snake) ni ibe  ibi iná(lice) ló mọ."
22/08/2026

"Irun ori ko ni kun ki a ba ejo(snake) ni ibe ibi iná(lice) ló mọ."

"Yorùbá sọ fún wa wípé: àmọ̀dún kò jìnnà kí akébùtà (someone who takes his yam sets to the market for sale) ko ma a rọ́j...
21/08/2026

"Yorùbá sọ fún wa wípé: àmọ̀dún kò jìnnà kí akébùtà (someone who takes his yam sets to the market for sale) ko ma a rọ́jú."

B'ERU BA KU OWO W'OGBO
20/08/2026

B'ERU BA KU OWO W'OGBO

AYE GBA EFO OGUNMO
19/08/2026

AYE GBA EFO OGUNMO

"Obìnrin tó ń gé igi nínú igbó òró, wọ́n ní kí lórúkọ rẹ̀? Ó ní Òun A GE MO (cutting my last)."
18/08/2026

"Obìnrin tó ń gé igi nínú igbó òró, wọ́n ní kí lórúkọ rẹ̀? Ó ní Òun A GE MO (cutting my last)."

"Àwọn àgbà bọ̀, wọ́n sọ wípé: ẹni tí ó ń dá nìkan rẹ́rìn-ín, ó ń pa ète àti ṣe ofofo."
17/08/2026

"Àwọn àgbà bọ̀, wọ́n sọ wípé: ẹni tí ó ń dá nìkan rẹ́rìn-ín, ó ń pa ète àti ṣe ofofo."

Address

Akute
Akute-Oja

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Adun Ede yoruba posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share