05/07/2025
ILE IFA UN MEJOR DESTINO 🌴
Àbórú àbóyé àbósíse 🟤🟢
Contáctanos 📲+525516974276
ÒYÈKÙ MÉJÌ IFA DICE
Òrúnmílà ni Órúpùú
M ni eruku ló yọ toro
Ọ ni orí tí yóó dádé ninu ajere idẹ ni tíí wá
Ọrùn tí yóó lo èjígbàrà Ìléké ninu ajere idẹ ni tii wá
Bebe Ìdí tí yọọ lo mósàajà aṣọ Ọba ti ńtanná yanran yanran
Ninu ajere idẹ ni tii wá
Mo ni baba, bewo ni a ó ṣe mọ orí ti yóó dádé
Mi ni baba, bawo ni a ó ṣe mọ ọrùn tí yóó lo èjìgbàrà ìlèkè
Mo ni baba, bawo ni a ó ṣe mọ, bebe ìdì ti yóó lo mósàajà
Aṣọ Ọba tí ńtanrán yanran yanran
Òrúnmílà ni, bí abá bímọ, tí o bá di ọjọ kẹta, bí wọn bá bi òun
Léèrè
Wọn yóó mọ orí tí yóó dádé
Wọn yóó mọ ọrùn ti yóó lo èjìgbàraà Ìlèkè
Wọn yóó mọ bebe idi tí yóó lo mọsàajà aṣọ Ọba tí ńtanná
Yanranyanran
Orí ti yóó dádé ní ńdi Ọba
Ọrùn ti yóó lo èjìgbàrà ìlèkè ni ńdi àwọn ìjòye
Bebe ìdi ti yóó mọsaàjà aṣọ Ọba ti ńtanná yanranyanran ni
Ńdi aya Ọba
Traducción:
Òrúnmílà declara: "ha surgido repentinamente
Respondo "es el polvo que salió despacio"
dice que "El sombrero principal gastaría la corona que viene del
Pote de latón de Ifá
el cuello que decoraría con cuentas múltiples
viene del pote del latón de Ifá
la cintura que lleva el traje del rey brillante viene
de pote del latón de Ifá
Pregunto: padre, cómo conocemos la cabeza que llevará la corona?
Pregunto: padre, cómo sabemos el cuello que sería
decorado con múltiples de cuentas?
Pregunto: "padre, cómo sabemos la cintura que gastaría el traje
del rey brillante?
Òrúnmílà contesta: "cuando damos a luz, durante el tercer día,
cuando consulta
Le diré la cabeza que llevará la corona
Le diré el cuello que se decoraría con cuentas múltiples
Le diré la cintura que llevaría el traje del rey brillante
La cabeza que llevaría la corona finalmente se hace el rey
el cuello que se decora con cuentas múltiples son
jefes tradicionales de los fabricantes del rey
la cintura que llevaría el traje del rey brillante son las reinas"
Ogbó ató asure ìwòrì ofun 🟢🟤