10/01/2021
’Alif lām mīm.
https://bit.ly/3pKmSDY
10/01/2021
’Alif lām mīm.
https://bit.ly/3pKmSDY
07/01/2021
’Alif lām mīm.
https://bit.ly/2KPxFy1
04/01/2021
Ní orúkọ Allāhu, Àjọkẹ́-ayé, Àṣàkẹ́-ọ̀run.
https://www.islamkingdom.com/yo/category/qurantrans
04/05/2020
SISENI NI AKIN ATI MAA SỌ ODODO , ATI KIKILỌ IRỌ P**A FUN NI
Eko ni soki
Ododo je iwa olola ninu ohun ti o maa npe igbagbo, ti o si maa npe Islam, nigbati Olohun Oba ti ola re ga paa ni ase, O si tun se eyin fun awon ti won ba gba iroyin pelu re, iwa ododo je ola fun awon olododo, o si je oso ati itutu oju fun eniti o ba jere pelu re. Nidamiran, iro je apejuwe ijanba ti o tobi, paapaa julo, o wa ninu awon apere pooki, ki yio si le eru kun ju ijinna si Olohun lo, eru ko ni ye ni eniti yio maa so ododo t**i ti won yio fi ko fun lodo Olohun wipe olododo ni, eru ko si ni ye ni imaa pa iro t**i ti won yio fi ko lodo Olohun wipe okuro ni.
https://www.global-minbar.com/yo/abala-iwa-siseni-ni-akin-ati-maa-s%E1%BB%8C-ododo-ati-kikil%E1%BB%8C-ir%E1%BB%8C-pipa-fun-ni
17/11/2019
02/08/2019
Ìsẹ̀mí wà fun yín nínú (òfin) ìgbẹ̀san ìpànìyàn, ẹ̀yin onílàákáyè, kí ẹ lè bẹ̀rù (Allāhu).
https://www.facebook.com/yoruba.minbar1/publishing_tools/?section=SCHEDULED_POSTS&sort[0]=scheduled_publish_time_ascending
30/07/2019
Ẹ̀yin ènìyàn, ẹ jẹ nínú ohun tí ń bẹ nínú ilẹ̀ (t’ó jẹ́) ẹ̀tọ́ (àti n̄ǹkan) dáadáa.Ẹ má sì ṣe tẹ̀lé àwọn ojú-ẹsẹ̀ Èṣù. Dájúdájú òun ni ọ̀tá pọ́nńbélé fun yín.
al-fatihah-1-saad-al-ghamdi-abu-rahimah-mikael-aykyuni- al-fatihah-saad-al-ghamdi-Ní orúkọ Allāhu, Àjọkẹ́-ayé, Àṣàkẹ́-ọ̀run.
30/07/2019
Ẹ̀yin tí ẹ gbàgbọ́ ní òdodo, ẹ jẹ nínú àwọn n̄ǹkan dáadáa tí A pèsè fun yín, kí ẹ sì dúpẹ́ fún Allāhu tí ó bá jẹ́ pé Òun nìkan ṣoṣo ni ẹ̀ ń jọ́sìn fún.
al-fatihah-1-saad-al-ghamdi-abu-rahimah-mikael-aykyuni- al-fatihah-saad-al-ghamdi-Ní orúkọ Allāhu, Àjọkẹ́-ayé, Àṣàkẹ́-ọ̀run.
27/07/2019
Ó sì ń bẹ nínú àwọn ènìyàn, ẹni tí ń jọ́sìn fún àwọn òrìṣà lẹ́yìn Allāhu. Wọ́n nífẹ̀ẹ́ wọn gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ (tó yẹ kí wọ́n ní sí) Allāhu. Àwọn t’ó gbàgbọ́ ní òdodo sì le jùlọ nínú ìfẹ́ sí Allāhu. Tí ó bá jẹ́ pé àwọn t’ó ṣàbòsí lè rí ìgbà tí wọ́n máa rí Ìyà náà ni, (wọn ìbá mọ̀ pé) dájúdájú gbogbo agbára ń jẹ́ ti Allāhu. Àti pé dájúdájú Allāhu le (níbi) ìyà.
al-fatihah-1-saad-al-ghamdi-abu-rahimah-mikael-aykyuni- al-fatihah-saad-al-ghamdi-Ní orúkọ Allāhu, Àjọkẹ́-ayé, Àṣàkẹ́-ọ̀run.
24/07/2019
Àwọn tí (ó jẹ́ pé) nígbà tí àdánwò kan bá kàn wọ́n, wọ́n á sọ pé: “Dájúdájú Allāhu l’Ó ni àwa; dájúdájú ọ̀dọ̀ Rẹ̀ sì ni àwa yóò padà sí.”
https://www.islamkingdom.com/yo/category/qurantrans?title=al-baqarah-saad-al-ghamdi-abu-rahimah-mikael-aykyuni-&pg=24&pa=2&su=2&sq=156&hz=3&rhz=9&ay=163&te=1&rd=701&tr=693&int=